× "...speaking to one another with psalms, hymns, and songs from the Spirit. Sing and make music from your heart to the Lord" - Ephesians 5:19

(VIDEO + AUDIO) TOPE ALABI - OBA NI FT TY BELLO

More
1 month 4 weeks ago #11543 by marvelatte
(VIDEO + LYRICS) Tope Alabi – Oba Ni Ft. TY Bello

 

Nigerian popular Iconic gospel powerhouse and songstress, Tope Alabi release a brand new song “Oba Ni” featuring TY Bello.

Oba Ni” is a song of worship and adoration to the eternal one, the ancient of days. The anointing in the song will uplift your spirits and lead you into a new worship experience.

WATCH THE VIDEO BELOW


Oba Ni Lyrics by Tope Alabi Ft. TY Bello (Lyrics)
Hallelujah Amen A,en
Kabi o Kosi O
Oluwa
Kabi o Kosi O
JesuKabi o Kosi O
Oluwa
Kabi o Kosi O
Jesu

Oba Ni
Lori aye gbogbo
Oba Ni
Lori Orun o
Oba loje
Lori Oun gbogbo to da
Oba ni o Oba ni o
Oba ni o

Kabi o Kosi O
Oluwa
Kabi o Kosi O
Jesu

Kabi o Kosi O
Oluwa
Kabi o Kosi O
Jesu

Oba Ni o
Lori aye gbogbo
Oba Ni
Lori Orun o
Oba loje
Lori Oun gbogbo to da
Oba ni o Oba ni o Oba ni o

Oba Ni o
Lori aye gbogbo
Oba Ni
Lori Eda gbogbo
Oba ni o
Lori aye gbogbo
Oba ni o Oba ni o Oba ni o

call: Oba ni o

Oba Ni o
Lori aye gbogbo
Oba Ni
Lori Orun o gbogbo
Oba loje
Lori aye gbogbo
Oba ni o Oba ni o Oba ni o

One more time
Oba Ni o
Lori aye gbogbo
Oba Ni
Lori Orun o gbogbo
Oba loje
Lori aye gbogbo
Oba ni o Oba ni o Oba ni o

Repeat

Ma sope oba ni
Oba ni o Oba ni o Oba ni o
Oba ni o Oba ni o Oba ni o

Interlude

Patapata ola
Ololu to lu aye
Olu aye aye odalu
Ogbe aye
Ogbe daadaa
Oun to da daadaa ni o
Oba ni o Oba ni o Oba ni o

Airiro ala
Oba ti n gbe ni ipekun orun
Gbengbeleku
To nda nibi to wu

Elemi to fi siwa
Oba ni o Oba ni o Oba ni o

Aah ah ah
Oba ni o Oba ni o Oba ni o

Igbe ndaye egan oran tete
Ani pa ninu ola
Tala ba fi owe ta lole ba o doba
Eni to ni gbogbo ipa ati agbara lowo
Iwo nikan lemi oma ki ti no ma ki

Ogbogbon ologbogbon
iwo nikan loni
Ola ogbogbo ki ogbon da gba
eni to gbogbo o n toda nrubo fun

Oba ni o Oba ni o Oba ni o
Oba ni o Oba ni o
eh Oba ni o

magbe owore soke
ma yi
Ma sope ogo ni fun oru ko re

he is King of kings
Oba ni o

he is Lord of Lords
Oba ni o

Oba ni o Oba ni o Oba ni o

speaking in tongues

iwo to joko ni kunkun orun
to nse ohun to wu o
Egbo tani
ta la le fi se ikeji re

kabio osi o
Oba ni o
kabio osi o
Oba ni o

There is nobody like him
o o
Oba ni o Oba ni o Oba ni o

Agbe oga latisale inu wa wa
Ajuba re olorun
awa ti ahun dagba yi o
ao dabi eni to ngbe losu loto

won gbe oga won yi ologo gbogbo orun won yin ologo
Attachments:

Please Log in or Create an account to join the conversation.

Share on these Platforms
  • Not Allowed: to create new topic.
  • Not Allowed: to reply.
  • Not Allowed: to edit your message.
Facebook Comments (Forum)
Time to create page: 0.129 seconds

RELATED POSTS